IYANDA AYOMIDE JOB

Meet IYANDA AYOMIDE JOB, an Academic Staff of Lagos State University.

Specialization

Literature And Culture

Designation

Assistant Lecturer

Department

Linguistics, African Languages and Communication Arts

Office

At the Linguistics, African Languages And Communication Arts department office

Visiting Hour

Appointment on Visitation important

Qualifications

# Certificate SchoolYear
1. M.A. (YORUBA) Lagos State University. ojo 2023

Current Research

AROKO AJEMO IBO ABO GEGE BI O TI HANDE NINU ASA YORUBA

Research Details

Oké àimoye ibọ ni àkíyèsí àti àkosilè ti fi hàn pé ó wà ninu àwùjọ Yorubá. Awọn ibọ náà ni à ń pè ní òrișà. A le şàpèjúwe wọn gégé bí àwọn eda tí orí șà dá fún àwọn ișé kan pàtàkì ninu àwujo. Eróngbà ișé yìí ni láti șe túpale rokò ajemó ibọ abo gégé bí ó ti hàndé ninu àșà Yorubá èyí țí ó fi àpadé àti àludé ipàrokò àti igbroko hàn ninu ibánisorọ̀ láwujo edá. Tiri méji ni a fi yànnàná isé iwádií yìí, àwọn náà ni, tíọ́ri sẹmiotikì ajemo àsa àti tíộri isegbèfábo. Ohun tí tiori semíótiikì ajemo àșà ń tepelę mộ ní àmì àti itumo tí à n fún-un ní ògangan ibi tí a tị lò ó nínu àwùjo kookan. Tiori yi ń șí ojú àwùjo sí àșà gégé bí i ohun èlò itesíwájú àti idàgbàsókè. Tiori işègbèfábo ní tirè dà bi i agbęnuso fún àwon obinrin láwùjo. Ohun tí isègbèfábo ń jà fún ní didogba  láàrín ako àti abo láwùjo wa. Ișé iwádií yii șàmúlò ogbn iwádìí ifrowánilénuwò. Àbájáde ișe iwádií șe àfihàn àwon àrokò ajemó ibọ tó ní ișe pèlú abo ninu àșà Yorùbá, ó sì jế kí á ní òye tí ó jinná ninu ewà tí ó rộ mộ wọn pàápàá julo, àwọn itumộ tí ó farasin. Ișé iwádií yìí tan imole sí àwọn ohun tí ó rújú, ó sì jé kí á ní ye tí ó yàtọ̀ sí tàtẹ̀yinwá ninu àrokò ajemó ibo abo ninu àșà Yorùbá.

Biography

IYANDA JOB is a Assistant Lecturer at the Department of Linguistics, African Languages and Communication Arts

IYANDA has a M.A. in YORUBA from Lagos State University. ojo

The Numbers Say it AllWhy Choose Us